Biblia Todo Logo
Bìoball air-loidhne

- Sanasan -




Johanu 1:23 - Yoruba Bible

23 Ó bá dáhùn gẹ́gẹ́ bí wolii Aisaya ti sọ pé: “Èmi ni ‘ohùn ẹni tí ń kígbe ninu aṣálẹ̀ pé: Ẹ ṣe ọ̀nà tí ó tọ́ fún Oluwa.’ ”

Faic an caibideil Dèan lethbhreac

Bibeli Mimọ

23 O wipe, Emi li ohùn ẹni ti nkigbe ni ijù, Ẹ ṣe ki ọ̀na Oluwa tọ́, gẹgẹ bi woli Isaiah ti wi.

Faic an caibideil Dèan lethbhreac

Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní

23 Johanu sì fi ọ̀rọ̀ wòlíì Isaiah fún wọn ní èsì pé, “Èmi ni ohùn ẹni tí ń kígbe ní ijù, ‘Ẹ ṣe ọ̀nà Olúwa ní títọ́.’ ”

Faic an caibideil Dèan lethbhreac




Johanu 1:23
9 Iomraidhean Croise  

Nítorí òun ni wolii Aisaya sọ nípa rẹ̀ pé, “Ohùn ẹnìkan tí ó ń kígbe ninu aṣálẹ̀ pé, ‘Ẹ la ọ̀nà tí OLUWA yóo gbà, ẹ ṣe é kí ó tọ́ fún un láti rìn.’ ”


Ohùn ẹni tí ń kígbe ninu aṣálẹ̀ pé, ‘Ẹ la ọ̀nà tí Oluwa yóo gbà, ẹ ṣe é kí ó tọ́ fún un láti rìn.’ ”


Wọ́n bá tún bèèrè pé, “Ó dára, ta ni ọ́? Ó yẹ kí á lè rí èsì mú pada fún àwọn tí wọ́n rán wa wá. Kí ni o sọ nípa ara rẹ?”


Àwọn Farisi ni ó rán àwọn eniyan sí i.


Ẹ̀yin fúnra yín jẹ́rìí mi pé mo sọ pé, ‘Èmi kì í ṣe Kristi náà, ṣugbọn èmi ni a rán ṣiwaju rẹ̀.’


Lean sinn:

Sanasan


Sanasan