Biblia Todo Logo
Bìoball air-loidhne

- Sanasan -




Gẹnẹsisi 5:9 - Yoruba Bible

9 Nígbà tí Enọṣi di ẹni aadọrun-un ọdún, ó bí Kenani.

Faic an caibideil Dèan lethbhreac

Bibeli Mimọ

9 Enoṣi si wà li ãdọrun ọdún, o si bí Kenani:

Faic an caibideil Dèan lethbhreac

Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní

9 Nígbà tí Enoṣi di ẹni àádọ́rùn-ún ọdún (90) ni ó bí Kenani.

Faic an caibideil Dèan lethbhreac




Gẹnẹsisi 5:9
4 Iomraidhean Croise  

Lẹ́yìn tí ó bí Kenani, ó gbé ẹgbẹrin ọdún ó lé mẹẹdogun (815) láyé, ó sì bí àwọn ọmọ mìíràn lọkunrin ati lobinrin.


Gbogbo ọdún tí Seti gbé láyé jẹ́ ẹẹdẹgbẹrun ọdún ó lé mejila (912), kí ó tó kú.


Enọṣi bí Kenaani, Kenaani bí Mahalaleli, Mahalaleli bí Jaredi;


ọmọ Metusela, ọmọ Enọku, ọmọ Jaredi, ọmọ Mahalaleli, ọmọ Kenani,


Lean sinn:

Sanasan


Sanasan