Gẹnẹsisi 5:6 - Yoruba Bible6 Nígbà tí Seti di ẹni ọdún marundinlaadọfa (105), ó bí Enọṣi. Faic an caibideilBibeli Mimọ6 Seti si wà li ọgọrun ọdún o lé marun, o si bí Enoṣi: Faic an caibideilBíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní6 Nígbà tí Seti pé àrùnlélọ́gọ́rùnún ọdún (105), ó bí Enoṣi. Faic an caibideil |