Gẹnẹsisi 5:12 - Yoruba Bible12 Nígbà tí Kenani di ẹni aadọrin ọdún, ó bí Mahalaleli. Faic an caibideilBibeli Mimọ12 Kenani si wà li ãdọrin ọdún, o si bí Mahalaleli: Faic an caibideilBíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní12 Nígbà tí Kenani di àádọ́rin ọdún (70) ni ó bí Mahalaleli: Faic an caibideil |