Gẹnẹsisi 5:11 - Yoruba Bible11 Gbogbo ọdún tí Enọṣi gbé láyé jẹ́ ẹẹdẹgbẹrun ọdún ó lé marun-un (905) kí ó tó kú. Faic an caibideilBibeli Mimọ11 Gbogbo ọjọ́ Enoṣi si jẹ ẹ̃dẹgbẹrun ọdún o lé marun: o si kú. Faic an caibideilBíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní11 Àpapọ̀ ọdún Enoṣi jẹ́ ẹ̀ẹ́dẹ́gbẹ̀rún-ọdún ó-lé-márùn-ún (905), ó sì kú. Faic an caibideil |