Gẹnẹsisi 2:6 - Yoruba Bible6 Ṣugbọn omi kan a máa ru jáde láti inú ilẹ̀ láti mú kí gbogbo ilẹ̀ rin. Faic an caibideilBibeli Mimọ6 Ṣugbọn ikũku a ti ilẹ wá, a si ma rin oju ilẹ gbogbo. Faic an caibideilBíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní6 Ṣùgbọ́n ìsun omi ń jáde láti ilẹ̀, ó sì ń bu omi rin gbogbo ilẹ̀. Faic an caibideil |