Gẹnẹsisi 2:22 - Yoruba Bible22 Ó fi egungun náà mọ obinrin kan, ó sì mú un tọ ọkunrin náà lọ. Faic an caibideilBibeli Mimọ22 OLUWA Ọlọrun si fi egungun-ìha ti o mu ni ìha ọkunrin na mọ obinrin, o si mu u tọ̀ ọkunrin na wá. Faic an caibideilBíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní22 Olúwa Ọlọ́run sì dá obìnrin láti inú egungun tí ó yọ ní ìhà ọkùnrin náà, Ó sì mu obìnrin náà tọ̀ ọ́ wá. Faic an caibideil |