Gẹnẹsisi 2:12 - Yoruba Bible12 Wúrà ilẹ̀ náà dára. Turari olówó iyebíye tí wọ́n ń pè ní bedeliumu, ati òkúta olówó iyebíye tí wọ́n ń pè ní onikisi wà níbẹ̀ pẹlu. Faic an caibideilBibeli Mimọ12 Wurà ilẹ na si dara: nibẹ ni bedeliumu (ojia) wà ati okuta oniki. Faic an caibideilBíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní12 (Wúrà ilẹ̀ náà dára, òjìá (bedeliumu) àti òkúta (óníkìsì) oníyebíye wà níbẹ̀ pẹ̀lú). Faic an caibideil |