Biblia Todo Logo
Bìoball air-loidhne

- Sanasan -




Gẹnẹsisi 10:3 - Yoruba Bible

3 Àwọn ọmọ Gomeri ni: Aṣikenasi, Rifati, ati Togama.

Faic an caibideil Dèan lethbhreac

Bibeli Mimọ

3 Ati awọn ọmọ Gomeri, Aṣkenasi, ati Rifati, ati Togarma.

Faic an caibideil Dèan lethbhreac

Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní

3 Àwọn ọmọ Gomeri ni: Aṣkenasi, Rifàti àti Togarma.

Faic an caibideil Dèan lethbhreac




Gẹnẹsisi 10:3
4 Iomraidhean Croise  

Gomeri ni baba ńlá àwọn ọmọ Aṣikenasi, Difati ati Togama.


“Ẹ ta àsíá sórí ilẹ̀ ayé, ẹ fun fèrè ogun láàrin àwọn orílẹ̀-èdè; kí àwọn orílẹ̀-èdè múra láti gbógun tì í, ẹ sì pe àwọn ìjọba jọ láti dojú kọ ọ́; àwọn ìjọba orílẹ̀-èdè bíi Ararati, Minni, ati Aṣikenasi. Ẹ yan balogun tí yóo gbógun tì í; ẹ kó ẹṣin wá, kí wọn pọ̀ bí eṣú.


Àwọn ará Beti Togama a máa kó ẹṣin, ati ẹṣin ogun, ati kẹ́tẹ́kẹ́tẹ́ wá ṣe pàṣípààrọ̀ àwọn nǹkan tí ò ń tà.


Gomeri ati gbogbo àwọn ọmọ ogun rẹ̀, ati Beti Togama láti òpin ilẹ̀ ìhà àríwá ati gbogbo àwọn ọmọ ogun rẹ̀; bẹ́ẹ̀ náà ni ọpọlọpọ orílẹ̀-èdè, wọ́n wà pẹlu rẹ̀.


Lean sinn:

Sanasan


Sanasan