Filemoni 1:3 - Yoruba Bible3 Kí oore-ọ̀fẹ́ wà pẹlu yín ati alaafia láti ọ̀dọ̀ Ọlọrun Baba wa, ati Oluwa Jesu Kristi. Faic an caibideilBibeli Mimọ3 Ore-ọfẹ, ati alafia sí nyin, lati ọdọ Ọlọrun Baba wa, ati Jesu Kristi Oluwa. Faic an caibideilBíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní3 Oore-Ọ̀fẹ́ fún un yín àti àlàáfíà láti ọ̀dọ̀ Ọlọ́run Baba wa àti Jesu Kristi. Faic an caibideil |