Biblia Todo Logo
Bìoball air-loidhne

- Sanasan -




Filemoni 1:25 - Yoruba Bible

25 Kí oore-ọ̀fẹ́ Oluwa Jesu Kristi kí ó wà pẹlu ẹ̀mí yín.

Faic an caibideil Dèan lethbhreac

Bibeli Mimọ

25 Ore-ọfẹ Jesu Kristi Oluwa wa ki o wà pẹlu ẹmí nyin. Amin.

Faic an caibideil Dèan lethbhreac

Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní

25 Kí oore-ọ̀fẹ́ Jesu Kristi Olúwa wa wà pẹ̀lú ẹ̀mí yín.

Faic an caibideil Dèan lethbhreac




Filemoni 1:25
4 Iomraidhean Croise  

Kí Ọlọrun orísun alaafia mu yín ṣẹgun Satani ní kíákíá. Kí oore-ọ̀fẹ́ Oluwa wa Jesu kí ó wà pẹlu yín.


Gaiyu náà ki yín. Òun ni ó gbà mí lálejò bí ó ti gba gbogbo ìjọ lálejò. Erastu, akápò ìlú, ki yín. Kuatu arakunrin wa náà ki yín. [


Ará, kí oore-ọ̀fẹ́ Jesu Kristi Oluwa wa kí ó wà pẹlu yín. Amin.


Kí Oluwa wà pẹlu ẹ̀mí rẹ. Kí oore-ọ̀fẹ́ wà pẹlu gbogbo yín.


Lean sinn:

Sanasan


Sanasan