Biblia Todo Logo
Bìoball air-loidhne

- Sanasan -




1 Peteru 2:3 - Yoruba Bible

3 Ó ṣá ti hàn si yín pé olóore ni Oluwa.

Faic an caibideil Dèan lethbhreac

Bibeli Mimọ

3 Bi ẹnyin ba ti tọ́ ọ wò pe, olõre li Oluwa:

Faic an caibideil Dèan lethbhreac

Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní

3 nísinsin yìí tí ẹ̀yin ti tọ́ ọ wò pé rere ni Olúwa.

Faic an caibideil Dèan lethbhreac




1 Peteru 2:3
8 Iomraidhean Croise  

Ta ni Ọba ògo yìí? OLUWA tí ó ní ipá tí ó sì lágbára, OLUWA tí ó lágbára lógun.


Tọ́ ọ wò, kí o sì rí i pé rere ni OLUWA! Ayọ̀ ń bẹ fún ẹni tí ó bá sá di í!


Ẹ̀mí mi yóo ní ànító ati àníṣẹ́kù; n óo sì fi ayọ̀ kọ orin ìyìn sí ọ.


Àwọn tí ó mọ̀ ọ́ yóo gbẹ́kẹ̀lé ọ; nítorí ìwọ, OLUWA, kìí kọ àwọn tí ń wá ọ sílẹ̀.


Bí igi ápù ti rí láàrin àwọn igi igbó, ni olùfẹ́ mí rí láàrin àwọn ọmọkunrin. Pẹlu ìdùnnú ńlá ni mo fi jókòó lábẹ́ òjìji rẹ̀, èso rẹ̀ sì dùn lẹ́nu mi.


Báwo ni ilẹ̀ náà yóo ti dára tó, yóo sì ti lẹ́wà tó? Ọkà yóo sọ àwọn ọdọmọkunrin di alágbára ọtí waini titun yóo sì fún àwọn ọdọmọbinrin ní okun.


Ṣugbọn nígbà tí Ọlọrun fi inú rere ati ìfẹ́ rẹ̀ sí àwa eniyan hàn, ó gbà wá là;


Lean sinn:

Sanasan


Sanasan