Numeri 9:4 - Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní4 Mose sì sọ fún àwọn ọmọ Israẹli pé kí wọ́n máa pa àjọ ìrékọjá mọ́. Faic an caibideilYoruba Bible4 Mose bá sọ fún àwọn ọmọ Israẹli kí wọ́n ṣe Àjọ̀dún ìrékọjá. Faic an caibideilBibeli Mimọ4 Mose si sọ fun awọn ọmọ Israeli ki nwọn ki o ma pa ajọ irekọja mọ́: Faic an caibideil |