Numeri 7:42 - Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní42 Eliasafu ọmọ Deueli olórí àwọn ọmọ Gadi ní ó mú ọrẹ rẹ̀ wá ní ọjọ́ kẹfà. Faic an caibideilYoruba Bible42 Ní ọjọ́ kẹfa ni Eliasafu, ọmọ Deueli, olórí àwọn ẹ̀yà Gadi, mú ọrẹ tirẹ̀ wá. Faic an caibideilBibeli Mimọ42 Li ọjọ́ kẹfa Eliasafu ọmọ Deueli, olori awọn ọmọ Gadi: Faic an caibideil |