40 Akọ ewúrẹ́ kan fún ẹbọ ẹ̀ṣẹ̀;
40 ati òbúkọ kan fún ẹbọ ìmúkúrò ẹ̀ṣẹ̀.
40 Akọ ewurẹ kan fun ẹbọ ẹ̀ṣẹ;
Akọ ọ̀dọ́ màlúù kan, àgbò kan àti akọ ọ̀dọ́-àgùntàn ọlọ́dún kan fún ẹbọ sísun;
Màlúù méjì, àgbò márùn-ún, akọ ewúrẹ́ márùn-ún àti akọ ọ̀dọ́-àgùntàn ọlọ́dún kan márùn-ún tí wọn ó fi rú ẹbọ àlàáfíà. Èyí ni ọrẹ Ṣelumieli ọmọ Suriṣaddai.