Numeri 7:26 - Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní26 Àwo wúrà kan tí ìwọ̀n rẹ̀ jẹ́ ṣékélì mẹ́wàá tí ó kún fún tùràrí; Faic an caibideilYoruba Bible26 Ṣíbí wúrà kan tí ìwọ̀n rẹ̀ jẹ́ ṣekeli mẹ́wàá tí ó sì kún fún turari. Faic an caibideilBibeli Mimọ26 Ṣibi kan ìwọn ṣekeli mẹwa wurà, o kún fun turari; Faic an caibideil |