Biblia Todo Logo
Bìoball air-loidhne

- Sanasan -




Numeri 7:22 - Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní

22 Akọ ewúrẹ́ kan fún ẹbọ ẹ̀ṣẹ̀;

Faic an caibideil Dèan lethbhreac

Yoruba Bible

22 òbúkọ kan fún ẹbọ ìmúkúrò ẹ̀ṣẹ̀.

Faic an caibideil Dèan lethbhreac

Bibeli Mimọ

22 Akọ ewurẹ kan fun ẹbọ ẹ̀ṣẹ;

Faic an caibideil Dèan lethbhreac




Numeri 7:22
3 Iomraidhean Croise  

Nígbà tí a bá sì sọ ẹ̀ṣẹ̀ rẹ̀ fún un, ó gbọdọ̀ mú akọ ewúrẹ́ tí kò ní àbùkù wá gẹ́gẹ́ bí ẹbọ rẹ̀.


Ọ̀dọ́ akọ màlúù kan, àgbò kan, àti akọ ọ̀dọ́-àgùntàn ọlọ́dún kan, fún ẹbọ sísun;


Màlúù méjì, àgbò márùn-ún, akọ ewúrẹ́ márùn-ún àti akọ ọ̀dọ́-àgùntàn ọlọ́dún kan márùn-ún tí wọn ó fi rú ẹbọ àlàáfíà. Èyí ni ọrẹ Netaneli ọmọ Ṣuari.


Lean sinn:

Sanasan


Sanasan