Numeri 7:21 - Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní21 Ọ̀dọ́ akọ màlúù kan, àgbò kan, àti akọ ọ̀dọ́-àgùntàn ọlọ́dún kan, fún ẹbọ sísun; Faic an caibideilYoruba Bible21 akọ mààlúù kékeré kan, àgbò kan ati ọ̀dọ́ àgbò kan, ọlọ́dún kan, fún ẹbọ sísun; Faic an caibideilBibeli Mimọ21 Ẹgbọrọ akọmalu kan, àgbo kan, akọ ọdọ-agutan kan ọlọdún kan, fun ẹbọ sisun; Faic an caibideil |