Biblia Todo Logo
Bìoball air-loidhne

- Sanasan -




Numeri 5:16 - Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní

16 “ ‘Àlùfáà yóò sì mú un wá síwájú Olúwa.

Faic an caibideil Dèan lethbhreac

Yoruba Bible

16 “Alufaa yóo sì mú kí obinrin náà dúró níwájú pẹpẹ OLUWA,

Faic an caibideil Dèan lethbhreac

Bibeli Mimọ

16 Ki alufa na ki o si mú u sunmọtosi, ki o mu u duro niwaju OLUWA:

Faic an caibideil Dèan lethbhreac




Numeri 5:16
6 Iomraidhean Croise  

“Èmi Olúwa ń wo ọkàn àti èrò inú ọmọ ènìyàn láti san èrè iṣẹ́ rẹ̀ fún un, gẹ́gẹ́ bí ọ̀nà rẹ̀ àti gẹ́gẹ́ bí iṣẹ́ ọwọ́ rẹ̀.”


“ ‘Bí ọrẹ ẹbọ náà bá jẹ́ ẹbọ sísun láti inú agbo ẹran kí òun kí ó mú akọ màlúù tí kò lábùkù. Ó sì gbọdọ̀ mú un wá sí ẹnu-ọ̀nà àgọ́ àjọ kí ó ba à lè jẹ́ ìtẹ́wọ́gbà níwájú Olúwa


nígbà náà ni ọkùnrin yìí yóò mú ìyàwó rẹ̀ lọ sọ́dọ̀ àlùfáà. Ọkùnrin náà yóò sì mú ọrẹ tí a yàn fún obìnrin náà, ìdámẹ́wàá òṣùwọ̀n efa ìyẹ̀fun barle. Kò gbọdọ̀ da òróró sí i, bẹ́ẹ̀ ni kò gbọdọ̀ fi tùràrí dídùn sí i nítorí pé ẹbọ ohun jíjẹ fún owú ni, èyí ti n mú ẹ̀ṣẹ̀ wá sí ìrántí.


Àlùfáà yóò sì bu erùpẹ̀ ilẹ̀ àgọ́ sínú omi mímọ́ tó bù láti ìkòkò amọ̀,


Kí ìgbéyàwó lọ́lá láàrín gbogbo ènìyàn, kí àkéte si jẹ́ aláìléèérí: Nítorí àwọn àgbèrè àti àwọn panṣágà ni Ọlọ́run yóò dá lẹ́jọ́.


Lean sinn:

Sanasan


Sanasan