Numeri 4:42 - Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní42 Wọ́n ka àwọn ọmọ Merari nípa ìdílé àti ilé baba wọn. Faic an caibideilYoruba Bible42 Àwọn tí a kà ninu àwọn ọmọ Merari, ní ìdílé-ìdílé gẹ́gẹ́ bí ilé baba wọn, Faic an caibideilBibeli Mimọ42 Awọn ti a si kà ni idile awọn ọmọ Merari, nipa idile wọn, gẹgẹ bi ile baba wọn, Faic an caibideil |