Numeri 4:40 - Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní40 Iye wọn nípa ìdílé àti ilé baba wọn jẹ́ ẹgbẹ̀tàlá ó-lé-ọgbọ̀n (2,630). Faic an caibideilYoruba Bible40 jẹ́ ẹgbẹtala ó lé ọgbọ̀n (2,630). Faic an caibideilBibeli Mimọ40 Ani awọn ti a kà ninu wọn, nipa idile wọn, gẹgẹ bi ile baba wọn, jẹ́ ẹgbẹtala o le ọgbọ̀n. Faic an caibideil |