Biblia Todo Logo
Bìoball air-loidhne

- Sanasan -




Numeri 4:36 - Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní

36 Iye wọn nípa ìdílé jẹ́ ẹgbẹ̀rìnlá ó-dínàádọ́ta (2,750).

Faic an caibideil Dèan lethbhreac

Yoruba Bible

36 Iye wọ́n jẹ́ ẹgbẹrinla ó dín aadọta (2,750).

Faic an caibideil Dèan lethbhreac

Bibeli Mimọ

36 Awọn ti a si kà ninu wọn nipa idile wọn jẹ́ ẹgbẹrinla o din ãdọta.

Faic an caibideil Dèan lethbhreac




Numeri 4:36
2 Iomraidhean Croise  

Gbogbo ọmọkùnrin láti ọmọ ọgbọ̀n ọdún títí dé àádọ́ta ọdún gbogbo àwọn tó ń wá ṣiṣẹ́ ní Àgọ́ ìpàdé.


Èyí ni àpapọ̀ iye àwọn ọmọ Kohati tó ń ṣiṣẹ́ ní àgọ́ ìpàdé; tí Mose àti Aaroni kà gẹ́gẹ́ bí Olúwa ti pa á láṣẹ fún Mose.


Lean sinn:

Sanasan


Sanasan