Numeri 4:22 - Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní22 “Tún ka iye àwọn ọmọ Gerṣoni nípa ilé baba wọn àti ìdílé wọn. Faic an caibideilYoruba Bible22 “Ka iye àwọn ọmọ Geriṣoni ní ìdílé-ìdílé, gẹ́gẹ́ bí ilé baba wọn: Faic an caibideilBibeli Mimọ22 Kà iye awọn ọmọ Gerṣoni pẹlu, gẹgẹ bi ile baba wọn, nipa idile wọn; Faic an caibideil |