Numeri 4:2 - Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní2 “Ka iye àwọn ọmọ Kohati láàrín àwọn ọmọ Lefi nípa ilé baba wọn àti ìdílé wọn. Faic an caibideilYoruba Bible2 “Ẹ ka iye àwọn ọmọ Kohati láàrin àwọn ọmọ Lefi, ní ìdílé-ìdílé, gẹ́gẹ́ bí ilé baba wọn. Faic an caibideilBibeli Mimọ2 Kà iye awọn ọmọ Kohati kuro ninu awọn ọmọ Lefi, nipa idile wọn, ile baba wọn, Faic an caibideil |