17 Olúwa sọ fún Mose àti Aaroni pé,
17 OLUWA sọ fún Mose ati Aaroni pé,
17 OLUWA si sọ fun Mose ati fun Aaroni pe,
“Iṣẹ́ Eleasari ọmọ Aaroni tí í ṣe àlùfáà ni ṣíṣe àbojútó òróró fìtílà, tùràrí dídùn, ẹbọ ohun jíjẹ ìgbà gbogbo àti òróró ìtasórí: Kí ó jẹ́ alábojútó gbogbo ohun tó jẹ mọ́ àgọ́ àti gbogbo ohun tó wà nínú rẹ̀, pẹ̀lú gbogbo ohun èlò ibi mímọ́.”
“Rí i pé a kò gé ẹ̀yà Kohati kúrò lára àwọn ọmọ Lefi: