Numeri 4:13 - Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní13 “Kí wọn ó kó eérú kúrò lórí pẹpẹ idẹ, kí wọn ó sì tẹ́ aṣọ aláwọ̀ àlùkò lé e lórí. Faic an caibideilYoruba Bible13 Wọn óo kó eérú kúrò lórí pẹpẹ, wọn óo fi aṣọ elése àlùkò bò ó. Faic an caibideilBibeli Mimọ13 Ki nwọn ki o si kó ẽru kuro lori pẹpẹ, ki nwọn ki o si nà aṣọ elesè-aluko kan bò o. Faic an caibideil |