Numeri 34:9 - Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní9 Tẹ̀síwájú lọ sí Sifroni, kí o sì fò pín si ní Hasari-Enani, Èyí yóò jẹ́ ààlà tìrẹ ní ìhà àríwá. Faic an caibideilYoruba Bible9 Sifironi ati Hasari Enani. Faic an caibideilBibeli Mimọ9 Opinlẹ rẹ yio si dé Sifroni, ati ijadelọ rẹ̀ yio dé Hasari-enani: eyi ni yio jẹ́ opinlẹ ìha ariwa nyin. Faic an caibideil |