Biblia Todo Logo
Bìoball air-loidhne

- Sanasan -




Numeri 32:10 - Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní

10 Ìbínú Olúwa sì dìde sí wọn ní ọjọ́ náà, ó sì búra, wí pé:

Faic an caibideil Dèan lethbhreac

Yoruba Bible

10 Nítorí náà ni ibinu Ọlọrun ṣe ru sí wọn nígbà náà. Ó sì búra pé,

Faic an caibideil Dèan lethbhreac

Bibeli Mimọ

10 Ibinu Ọlọrun si rú si wọn nigbana, o si bura, wipe,

Faic an caibideil Dèan lethbhreac




Numeri 32:10
8 Iomraidhean Croise  

Nítorí náà ni mo kéde ìbúra nínú ìbínú mi ‘Wọn kì yóò wọ ibi ìsinmi mi.’ ”


Nítorí náà, mo tún gbọ́wọ́ mi sókè ní ìbúra fún wọn nínú aginjù pé, èmi kì yóò mú wọn dé ilẹ̀ tí mo fi fún wọn—ilẹ̀ tí ó ń sàn fún wàrà àti oyin, ilẹ̀ tí ó lẹ́wà jùlọ láàrín àwọn ilẹ̀ yòókù.


Olúwa sọ fún Mose pé, “Fún ìgbà wo ni àwọn ènìyàn yìí yóò ti kẹ́gàn mi tó? Báwo ni yóò ti pẹ́ tó tí wọ́n ó fi kọ̀ jálẹ̀ láti gbà mí gbọ́, pẹ̀lú gbogbo iṣẹ́ ààmì tí mo ṣe láàrín wọn?


Ṣùgbọ́n nítòótọ́ bí mo ti wà láààyè, gbogbo ayé yóò kún fún ògo Olúwa.


Ọ̀kan nínú wọn kò ní rí ilẹ̀ náà tí mo ṣe ìlérí ní ìbúra láti fún baba ńlá wọn. Kò sí ọ̀kan nínú àwọn tó kẹ́gàn mi tí yóò rí ilẹ̀ náà.


Nínú aginjù yìí ni ẹ ó kú sí, gbogbo ẹ̀yin tí ẹ kùn láti ọmọ ogún ọdún ó lé àní gbogbo ẹ̀yin tí a kà.


Lean sinn:

Sanasan


Sanasan