Biblia Todo Logo
Bìoball air-loidhne

- Sanasan -




Numeri 3:48 - Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní

48 Owó tí a fi ra àwọn àkọ́bí ọmọ Israẹli tó lé yìí, ni kí o kó fún Aaroni àti àwọn ọmọ rẹ̀.

Faic an caibideil Dèan lethbhreac

Yoruba Bible

48 Kí o sì kó owó náà fún Aaroni ati àwọn ọmọ rẹ̀.”

Faic an caibideil Dèan lethbhreac

Bibeli Mimọ

48 Ki o si fi ninu owo na, ani owo ìrapada ti o lé ninu wọn, fun Aaroni ati fun awọn ọmọ rẹ̀.

Faic an caibideil Dèan lethbhreac




Numeri 3:48
3 Iomraidhean Croise  

ìwọ yóò gba ṣékélì márùn-ún (5) lórí ẹni kọ̀ọ̀kan gẹ́gẹ́ bí iye owó ibi mímọ́, èyí tí í ṣe ogún gera.


Nígbà náà ni Mose gba owó ìràpadà àwọn ènìyàn tó ṣẹ́kù lẹ́yìn tí àwọn ọmọ Lefi ti ra àwọn yòókù padà.


Mose sì kó owó ìràpadà yìí fún Aaroni àti àwọn ọmọ rẹ̀, bí Olúwa ti pa á láṣẹ fún un.


Lean sinn:

Sanasan


Sanasan