Numeri 3:42 - Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní42 Mose sì ka gbogbo àkọ́bí àwọn ọmọ Israẹli gẹ́gẹ́ bí Olúwa ti pàṣẹ fún un. Faic an caibideilYoruba Bible42 Mose bá ka gbogbo àwọn àkọ́bí ninu àwọn ọmọ Israẹli gẹ́gẹ́ bí OLUWA ti pàṣẹ fún un. Faic an caibideilBibeli Mimọ42 Mose si kà gbogbo awọn akọ́bi ninu awọn ọmọ Israeli, bi OLUWA ti paṣẹ fun u. Faic an caibideil |