Numeri 3:30 - Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní30 Olórí àwọn ìdílé Kohati ni Elisafani ọmọ Usieli. Faic an caibideilYoruba Bible30 Elisafani ọmọ Usieli ni yóo jẹ́ olórí wọn. Faic an caibideilBibeli Mimọ30 Ati Elisafani ọmọ Usieli ni ki o ṣe olori ile baba awọn idile awọn ọmọ Kohati. Faic an caibideil |
“Lẹ́yìn tí Aaroni àti àwọn ọmọ rẹ̀ ti parí bíbo ibi mímọ́ àti gbogbo ohun èlò ibi mímọ́, nígbà tí àgọ́ bá sì ṣetán láti tẹ̀síwájú, kí àwọn ọmọ Kohati bọ́ síwájú láti gbé e, ṣùgbọ́n wọn kò gbọdọ̀ fọwọ́ kan ohun mímọ́ kankan, bí wọ́n bá ṣe bẹ́ẹ̀ wọn ó kú. Àwọn ọmọ Kohati ni yóò gbé gbogbo ohun tó wà nínú àgọ́ ìpàdé.