Numeri 27:10 - Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní10 Tí kò bá ní arákùnrin, fi ogún ìní rẹ̀ fún arákùnrin baba rẹ̀. Faic an caibideilYoruba Bible10 Bí kò bá ní arakunrin, kí ẹ fi ilẹ̀ ìní rẹ̀ fún àwọn arakunrin baba rẹ̀. Faic an caibideilBibeli Mimọ10 Bi on kò ba si lí arakunrin, njẹ ki ẹnyin ki o fi ilẹ-iní rẹ̀ fun awọn arakunrin baba rẹ̀: Faic an caibideil |