Biblia Todo Logo
Bìoball air-loidhne

- Sanasan -




Numeri 26:61 - Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní

61 Ṣùgbọ́n Nadabu àti Abihu kú, nígbà tí wọ́n rú ẹbọ níwájú Olúwa nígbà tí wọ́n mú iná àjèjì wá.)

Faic an caibideil Dèan lethbhreac

Yoruba Bible

61 Nadabu ati Abihu kú nígbà tí wọ́n rúbọ sí OLUWA ninu Àgọ́ Àjọ pẹlu iná tí kò mọ́.

Faic an caibideil Dèan lethbhreac

Bibeli Mimọ

61 Ati Nadabu ati Abihu kú, nigbati nwọn mú iná ajeji wá siwaju OLUWA.

Faic an caibideil Dèan lethbhreac




Numeri 26:61
4 Iomraidhean Croise  

Aaroni fẹ́ Eliṣeba ọmọbìnrin Amminadabu tí í ṣe arábìnrin Nahiṣoni, ó sì bí Nadabu, Abihu, Eleasari àti Itamari.


Ṣùgbọ́n Nadabu àti Abihu ti kú níwájú Olúwa nígbà tí wọ́n rú iná àjèjì níwájú Olúwa nínú ijù Sinai, àwọn méjèèjì kò sì ní ọmọ. Báyìí Eleasari àti Itamari ló ṣiṣẹ́ àlùfáà nígbà ayé Aaroni baba wọn.


Lean sinn:

Sanasan


Sanasan