Biblia Todo Logo
Bìoball air-loidhne

- Sanasan -




Numeri 26:45 - Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní

45 Ti àwọn ọmọ Beriah: ti Heberi, ìdílé àwọn ọmọ Heberi; ti Malkieli, ìdílé àwọn ọmọ Malkieli.

Faic an caibideil Dèan lethbhreac

Yoruba Bible

45 Àwọn ọmọ Beria ni: ìdílé Heberi ati ìdílé Malikieli.

Faic an caibideil Dèan lethbhreac

Bibeli Mimọ

45 Ti awọn ọmọ Beria: ti Heberi, idile awọn ọmọ Heberi: ti Malkieli, idile awọn ọmọ Malkieli.

Faic an caibideil Dèan lethbhreac




Numeri 26:45
3 Iomraidhean Croise  

Àwọn ọmọkùnrin Aṣeri: Imina, Iṣifa, Iṣfi àti Beriah. Arábìnrin wọn ni Sera. Àwọn ọmọkùnrin Beriah: Heberi àti Malkieli.


Ti àwọn ọmọ Aṣeri gẹ́gẹ́ bí ìdílé wọn: ti Imina, ìdílé àwọn ọmọ Imina; ti Iṣfi, ìdílé àwọn ọmọ Iṣfi; ti Beriah, ìdílé àwọn ọmọ Berii;


(Orúkọ ọmọ Aṣeri obìnrin nì jẹ́ Sera.)


Lean sinn:

Sanasan


Sanasan