Biblia Todo Logo
Bìoball air-loidhne

- Sanasan -




Numeri 26:43 - Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní

43 Gbogbo ìdílé àwọn ọmọ Ṣuhamu, gẹ́gẹ́ bí àwọn tí a kà nínú wọn jẹ́ ẹgbàá-méjìlélọ́gbọ̀n ó-lé-irínwó (64,400).

Faic an caibideil Dèan lethbhreac

Yoruba Bible

43 Gbogbo àwọn tí a kà ninu ẹ̀yà Dani jẹ́ ẹgbaa mejilelọgbọn ó lé irinwo (64,400).

Faic an caibideil Dèan lethbhreac

Bibeli Mimọ

43 Gbogbo idile awọn ọmọ Ṣuhamu, gẹgẹ bi awọn ti a kà ninu wọn, nwọn jẹ́ ẹgba mejilelọgbọ̀n o le irinwo.

Faic an caibideil Dèan lethbhreac




Numeri 26:43
3 Iomraidhean Croise  

Wọ̀nyí ni àwọn ọmọ Dani gẹ́gẹ́ bí ìdílé wọn: ti Ṣuhamu, ìdílé àwọn ọmọ Ṣuhamu Wọ̀nyí ni ìdílé Dani gẹ́gẹ́ bí ìdílé wọn:


Lean sinn:

Sanasan


Sanasan