Biblia Todo Logo
Bìoball air-loidhne

- Sanasan -




Numeri 26:42 - Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní

42 Wọ̀nyí ni àwọn ọmọ Dani gẹ́gẹ́ bí ìdílé wọn: ti Ṣuhamu, ìdílé àwọn ọmọ Ṣuhamu Wọ̀nyí ni ìdílé Dani gẹ́gẹ́ bí ìdílé wọn:

Faic an caibideil Dèan lethbhreac

Yoruba Bible

42 Àwọn ọmọ Dani ní ìdílé-ìdílé nìwọ̀nyí: ìdílé Ṣuhamu.

Faic an caibideil Dèan lethbhreac

Bibeli Mimọ

42 Wọnyi li awọn ọmọ Dani gẹgẹ bi idile wọn: ti Ṣuhamu, idile awọn ọmọ Ṣuhamu. Wọnyi ni idile Dani gẹgẹ bi idile wọn.

Faic an caibideil Dèan lethbhreac




Numeri 26:42
4 Iomraidhean Croise  

Àwọn ọmọ Dani: Huṣimu.


Láti ìran Dani: Gbogbo ọmọkùnrin tí ọjọ́ orí wọn jẹ́ ọmọ ogún ọdún sókè, tí wọ́n lè lọ sójú ogun ni wọ́n to orúkọ wọn lẹ́yọ kọ̀ọ̀kan gẹ́gẹ́ bí àkọsílẹ̀ ẹbí àti ìdílé wọn.


Wọ̀nyí ni àwọn ọmọ Benjamini; gẹ́gẹ́ bí ìdílé wọn; àti àwọn tí a kà nínú wọn jẹ́ ẹgbàá-méjìlélógún ó-lé-ẹgbẹ̀jọ (45,600).


Gbogbo ìdílé àwọn ọmọ Ṣuhamu, gẹ́gẹ́ bí àwọn tí a kà nínú wọn jẹ́ ẹgbàá-méjìlélọ́gbọ̀n ó-lé-irínwó (64,400).


Lean sinn:

Sanasan


Sanasan