Numeri 26:40 - Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní40 Àwọn ọmọ Bela ní ipasẹ̀ Ardi àti Naamani nìyìí: ti Ardi, ìdílé àwọn ọmọ Ardi; ti Naamani, ìdílé àwọn ọmọ Naamani. Faic an caibideilYoruba Bible40 Àwọn ọmọ Bela nìwọ̀nyí: ìdílé Aridi ati ìdílé Naamani. Faic an caibideilBibeli Mimọ40 Awọn ọmọ Bela si ni Ardi ati Naamani: ti Ardi, idile awọn ọmọ Ardi: ati ti Naamani, idile awọn ọmọ Naamani. Faic an caibideil |