Biblia Todo Logo
Bìoball air-loidhne

- Sanasan -




Numeri 26:36 - Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní

36 Wọ̀nyí ni àwọn ọmọ Ṣutelahi: ti Erani, ìdílé àwọn ọmọ Erani;

Faic an caibideil Dèan lethbhreac

Yoruba Bible

36 Àwọn ọmọ Ṣutela nìwọ̀nyí, ìdílé Erani.

Faic an caibideil Dèan lethbhreac

Bibeli Mimọ

36 Wọnyi li awọn ọmọ Ṣutela: ti Erani, idile awọn ọmọ Erani.

Faic an caibideil Dèan lethbhreac




Numeri 26:36
3 Iomraidhean Croise  

Àwọn ìran ọmọ Efraimu: Ṣutelahi, Beredi ọmọkùnrin rẹ̀, Tahati ọmọ rẹ̀, Eleadah ọmọ rẹ̀. Tahati ọmọ rẹ̀


Wọ̀nyí ni àwọn ọmọ Efraimu gẹ́gẹ́ bí ìdílé wọn: láti ọ̀dọ̀ Ṣutelahi, ìdílé àwọn ọmọ Ṣutelahi; ti Bekeri, ìdílé àwọn ọmọ Bekeri; ti Tahani, ìdílé àwọn ọmọ Tahani.


Wọ̀nyí ni ìdílé àwọn ọmọ Efraimu, àwọn tí a kà nínú wọn sì jẹ́ ẹgbàá-mẹ́rìn-dínlógún ó-lé-ẹ̀ẹ́dẹ́gbẹ̀ta (32,500). Wọ̀nyí ni àwọn ọmọ Josẹfu gẹ́gẹ́ bí ìdílé wọn.


Lean sinn:

Sanasan


Sanasan