Numeri 26:23 - Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní23 Àwọn ọmọ Isakari gẹ́gẹ́ bí ìdílé wọn: ti Tola, ìdílé Tola; ti Pufa, ìdílé Pufa; Faic an caibideilYoruba Bible23 Àwọn ọmọ Isakari ní ìdílé-ìdílé nìwọ̀nyí: ìdílé Tola, ìdílé Pua; Faic an caibideilBibeli Mimọ23 Awọn ọmọ Issakari gẹgẹ bi idile wọn: ti Tola, idile Tola: ti Pufa, idile Pufa: Faic an caibideil |