Numeri 26:19 - Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní19 Àwọn ọmọ Juda ni Eri àti Onani, ṣùgbọ́n Eri àti Onani kú ní ilẹ̀ Kenaani. Faic an caibideilYoruba Bible19 Àwọn ọmọ Juda ni Eri ati Onani. Eri ati Onani kú ní ilẹ̀ Kenaani. Faic an caibideilBibeli Mimọ19 Awọn ọmọ Juda, ni Eri ati Onani: ati Eri ati Onani kú ni ilẹ Kenaani. Faic an caibideil |