Numeri 26:14 - Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní14 Wọ̀nyí ni ìdílé àwọn ọmọ Simeoni, ẹgbàá-mọ́kànlá ó-lé-igba. (22,200) ọkùnrin. Faic an caibideilYoruba Bible14 Gbogbo àwọn tí a kà ninu ẹ̀yà Simeoni jẹ́ ẹgbaa mọkanla ó lé igba (22,200). Faic an caibideilBibeli Mimọ14 Wọnyi ni idile awọn ọmọ Simeoni, ẹgba mọkanla o le igba. Faic an caibideil |