Biblia Todo Logo
Bìoball air-loidhne

- Sanasan -




Numeri 26:13 - Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní

13 ti Sera, ìdílé Sera; tí Saulu, ìdílé Saulu.

Faic an caibideil Dèan lethbhreac

Yoruba Bible

13 ìdílé Sera ati ti Ṣaulu.

Faic an caibideil Dèan lethbhreac

Bibeli Mimọ

13 Ti Sera, idile Sera: ti Ṣaulu, idile Ṣaulu.

Faic an caibideil Dèan lethbhreac




Numeri 26:13
6 Iomraidhean Croise  

Àwọn ọmọkùnrin Simeoni: Jemueli, Jamini, Ohadi, Jakini, Sohari àti Saulu, tí ìyá rẹ̀ jẹ́ ọmọbìnrin ará Kenaani.


Ẹ̀kẹjọ fún oṣù kẹjọ jẹ́ Sibekai ará Huṣati, ará Sera ọkùnrin ẹgbàá-méjìlá (24,000) ni ó wà ní ìpín rẹ̀.


Ẹ̀kẹwàá fún oṣù kẹwàá jẹ́ Maharai ará Netofa, ará Sera ọkùnrin ẹgbàá-méjìlá (24,000) ni ó wà ní ìpín rẹ̀.


Àwọn ọmọ ìran Simeoni bí ìdílé wọn: ti Nemueli, ìdílé Nemueli; ti Jamini, ìdílé Jamini; ti Jakini, ìdílé Jakini;


Wọ̀nyí ni ìdílé àwọn ọmọ Simeoni, ẹgbàá-mọ́kànlá ó-lé-igba. (22,200) ọkùnrin.


Àwọn agbo ilé e Juda wá sí iwájú, ó sì mú agbo ilé Sera. Ó sì mú agbo ilé Sera wá síwájú ní ìdílé kọ̀ọ̀kan, a sì mú ìdílé Sabdi.


Lean sinn:

Sanasan


Sanasan