Numeri 23:18 - Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní18 Nígbà náà ó bẹ̀rẹ̀ ọ̀rọ̀ sísọ: “Dìde, Balaki; kí o sì gbọ́ mi ọmọ Sippori. Faic an caibideilYoruba Bible18 Balaamu bá bẹ̀rẹ̀ sí fi òwe sọ̀rọ̀, ó ní: “Balaki, dìde, wá gbọ́, fetí sí mi, ọmọ Sipori; Faic an caibideilBibeli Mimọ18 O si bẹ̀rẹsi owe rẹ̀, o si wipe, Dide, Balaki, ki o si gbọ́; ki o si fetisi mi, iwọ ọmọ Sipporu: Faic an caibideil |