Numeri 22:2 - Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní2 Nísinsin yìí, Balaki ọmọ Sippori rí gbogbo ohun tí àwọn Israẹli ti ṣe sí àwọn ará Amori, Faic an caibideilYoruba Bible2 Nígbà tí Balaki ọmọ Sipori, ọba Moabu rí gbogbo ohun tí àwọn ọmọ Israẹli ṣe sí àwọn ará Amori, Faic an caibideilBibeli Mimọ2 Balaki ọmọ Sippori si ri gbogbo eyiti Israeli ti ṣe si awọn ọmọ Amori. Faic an caibideil |