Numeri 22:16 - Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní16 Wọ́n lọ sí ọ̀dọ̀ Balaamu wọ́n sì sọ pé: “Èyí ni ohun tí Balaki ọmọ Sippori sọ: Má ṣe jẹ́ kí ohunkóhun kí ó dè ọ́ lọ́nà láti wá sí ọ̀dọ̀ mi, Faic an caibideilYoruba Bible16 Wọ́n jíṣẹ́ fún un pé Balaki ní, “Mo bẹ̀ ọ́, má jẹ́ kí ohunkohun dí ọ lọ́wọ́ láti wá sọ́dọ̀ mi. Faic an caibideilBibeli Mimọ16 Nwọn tọ̀ Balaamu wá, nwọn si wi fun u pe, Bayi ni Balaki ọmọ Sippori wi pe, Emi bẹ̀ ọ, máṣe jẹ ki ohun kan ki o di ọ lọwọ lati tọ̀ mi wá: Faic an caibideil |