Numeri 22:10 - Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní10 Balaamu sọ fún Ọlọ́run pé, “Balaki ọmọ Sippori, ọba Moabu, rán iṣẹ́ yìí sí mi pé: Faic an caibideilYoruba Bible10 Balaamu dáhùn pé, “Balaki ọba àwọn ará Moabu ni ó rán wọn sí mi pé, Faic an caibideilBibeli Mimọ10 Balaamu si wi fun Ọlọrun pe, Balaki ọmọ Sippori, ọba Moabu, li o ranṣẹ si mi pe, Faic an caibideil |