Biblia Todo Logo
Bìoball air-loidhne

- Sanasan -




Numeri 21:15 - Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní

15 àti ní ìṣàn odò tí ó darí sí ibùjókòó Ari tí ó sì fi ara ti ìpínlẹ̀ Moabu.”

Faic an caibideil Dèan lethbhreac

Yoruba Bible

15 ati ní gẹ̀rẹ́gẹ̀rẹ́ àwọn àfonífojì náà tí ó lọ títí dé ìlú Ari, tí ó lọ dé ààlà Moabu.”

Faic an caibideil Dèan lethbhreac

Bibeli Mimọ

15 Ati ni iṣàn-odò nì ti o darí si ibujoko Ari, ti o si gbè ipinlẹ Moabu.

Faic an caibideil Dèan lethbhreac




Numeri 21:15
6 Iomraidhean Croise  

Ọ̀rọ̀-ìmọ̀ tí ó kan Moabu: A pa Ari run ní Moabu, òru kan ní a pa á run! A pa Kiri run ní Moabu, òru kan ní a pa á run!


Ìdí nìyìí tí ìwé ogun Olúwa se wí pé: “…Wahebu ní Sufa, Òkun pupa àti ní odò Arnoni


“Iná jáde láti Heṣboni, ọ̀wọ́-iná láti Sihoni. Ó jó Ari àti Moabu run, àti ìlú àwọn olùgbé ibi gíga Arnoni.


“Lónìí ni ẹ̀yin yóò la agbègbè Moabu kọjá ní Ari.


gẹ́gẹ́ bí àwọn ọmọ Esau tí ó ń gbé ní Seiri àti àwọn ará Moabu tí ó ń gbé ní Ari, ti gbà wá láààyè títí a fi la Jordani já dé ilẹ̀ tí Olúwa Ọlọ́run wa yóò fún wa.”


Olúwa sì sọ fún mi pé, “Ẹ má ṣe dẹ́rùba àwọn ará Moabu bẹ́ẹ̀ ni kí ẹ má ṣe bá wọn jagun torí pé n kò ní fi èyíkéyìí nínú ilẹ̀ wọn fún un yín. Mo ti fi Ari fún àwọn ọmọ Lọti bí i ìní.”


Lean sinn:

Sanasan


Sanasan