Numeri 21:12 - Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní12 Láti ibẹ̀ ni wọ́n ti gbéra wọ́n sì pa ibùdó ní Àfonífojì Seredi. Faic an caibideilYoruba Bible12 Wọ́n gbéra láti ibẹ̀, wọ́n lọ pa àgọ́ sí àfonífojì Seredi. Faic an caibideilBibeli Mimọ12 Lati ibẹ̀ lọ nwọn ṣí, nwọn si dó si afonifoji Seredi. Faic an caibideil |