Numeri 2:8 - Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní8 Iye ìpín rẹ̀ jẹ́ ẹgbàá-méjì-dínlọ́gbọ̀n ó-lé-egbèje (57,400). Faic an caibideilYoruba Bible8 Àwọn ọmọ ogun tí a kà ninu wọn jẹ́ ẹgbaa mejidinlọgbọn ó lé egbeje (57,400). Faic an caibideilBibeli Mimọ8 Ati ogun rẹ̀, ati awọn ti a kà ninu wọn, jẹ́ ẹgba mejidilọgbọ̀n o le egbeje. Faic an caibideil |