Numeri 2:4 - Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní4 Iye ìpín rẹ̀ jẹ́ ẹgbàá-mẹ́tàdínlógójì ó-lé-ẹgbẹ̀ta (74,600). Faic an caibideilYoruba Bible4 Àwọn ọmọ ogun tí a kà ninu wọn jẹ́ ẹgbaa mẹtadinlogoji ó lé ẹgbẹta (74,600). Faic an caibideilBibeli Mimọ4 Ati ogun rẹ̀, ati awọn ti a kà ninu wọn, jẹ́ ẹgba mẹtadilogoji o le ẹgbẹta. Faic an caibideil |